Kumuyi bible: ọdún mẹ́ẹ̀dógún ni òun àtàwọn onímọ̀ yorùbá fi ṣe ìwádìí nípa bíbélì náà - bbc news yorùbá

Bbc

Kumuyi bible: ọdún mẹ́ẹ̀dógún ni òun àtàwọn onímọ̀ yorùbá fi ṣe ìwádìí nípa bíbélì náà - bbc news yorùbá"

Play all audios:

Loading...

KUMUYI BIBLE: ỌDÚN MẸ́Ẹ̀DÓGÚN NI ÒUN ÀTÀWỌN ONÍMỌ̀ YORÙBÁ FI ṢE ÌWÁDÌÍ NÍPA BÍBÉLÌ NÁÀ 3 Òkùdu 2019 Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn 29 Agẹmo 2020 LAIPẸ YII NI ALUFA AGBA FUN ÌJỌ DEEPER


CHRISTIAN LIFE MINISTRY, W. F KUMUYI, GBE BIBELI YORUBA TO ṢE JÁDE. Bibeli tuntun yii si ni ko tii rinlẹ laarin awọn onigbagbọ, to si tun kun ara awọn Bibeli miran to ti wa nilẹ tẹlẹ. Ninu


ọrọ kan to sọ, Bibeli naa to pe ni Bibeli Mimo Atoka, Kumuyi sọ pe, oun sisẹ pọ pẹlu awọn onimọ èdè Yoruba fun ọdun mẹẹdogun, fun iwadii to yẹ, ki kikọ ati títẹ̀ rẹ to o pari. ÀWỌN IRÒYIN TÌ


Ẹ LEÈ NÍ ÌFẸ̀ SÍÍ: * Oríire dé! Sanwo-Olu fẹ́ fojú-rinjú pẹ̀lú ọmọ tó ní kí ìyá òun ‘Calm down’ * Mamman Daura rí ìjà ọmọ Nàíjíríà torí ó pè fún wíwọ́gilé pínpín ipò ààrẹ lẹ́lẹ́kùn jẹkùn *


Ìkúnlẹ̀ abiyamọ, ìkókó mẹ́jọ kú nílé ìwòsàn lálẹ́ ọjọ́ kàn * Dayo Amusa gbarata lórí bí agbófinró ṣe ń pa ọ̀dọ́ láì nídìí * Ẹyìn tí Hydroxychloroquine, Zinc ati Zithromax da lára yá,ẹ bọ


síta wà jẹrìí mí-Dr Stella Emmanuel KI NI AWỌN NNKAN TO WA NINU BIBELI NAA? Gẹgẹ bi Alufa Kumuyi ṣe sọ, awọn amuyẹ yii ni Bibeli Mimọ Atọka naa ni: * Ọdun mẹẹdogun lo gba ki wọn o to o tẹ


sita * Kii ṣe pe Alufa Kumuyi kọ bibeli miran, amọ, o sọ pe oun ṣe ogbufọ ede oyinbo ni, sugbọn ni ede Yoruba to rọrùn lati kà fún ẹnikẹni * Ẹgbẹ awọn oluka Bibeli, Bible Society of Nigeria,


lo ba Kumuyi tẹ bibeli naa sita * Kumuyi sọ pe o jẹ ọkan lara awọn Bibeli òde oni, to ṣe e gbarale, to si rọrun julọ lati kà * Ẹgbẹrun mẹta ati ọtalelẹgbẹrin din mẹwaa Naira (₦3,750) ni wọn


n ta ẹyọ kan Bibeli naa * Bibeli naa jẹ kikọ ni ilana èdè Yoruba ode oni, nípa ṣíṣe agbeyẹwo awọn ọrọ akọtọ ati gbolohun ede Yoruba to ti yi pada kuro ni ti àtijọ́ * Ilana lori bi a ṣe n pe


ọrọ Yoruba kọọkan, ati itumọ awọn ọrọ to ta koko * Kumuyi sọ pe Bibeli naa wulo fun ẹ̀kọ́ Bibeli ati iwaasu, bẹẹ ni ko yi ohunkohun pada ninu Bibeli to ti wa tẹlẹ. Ni nkan bi ọdun 1850 ni


wọn kọkọ gbe Bibeli jade ni èdè Yoruba, lati ọwọ Oloogbe Ajayi Crowther, to jẹ ọmọ bibi ìlú Osoogun nipinlẹ Oyo. Skip Èyítí A Ń Kà Jùlọ and continue reading ÈYÍTÍ A Ń KÀ JÙLỌ * Ọwọ́ ológun


Nàìjíríà tẹ ṣọ́ja 18, ọ̀lọ́pàá 15, fẹ̀sùn kan àwọn àjọ òkèèrè tó ń ṣe agbódegbà fáwọn agbésùnmọ̀mí * Ìtàn ayé Orúgbó, ìyá àgbà tó dá ìlú Omu-Aran sílẹ̀ ní 13th Century àmọ̀ tí wọn ‘ló wa


láyé di òní’ * Regina Chukwu sọ ìdí tí ọkọ rẹ̀ ṣe ní kò gún òun ní abẹ́rẹ́ ikú lẹ́yìn ọdún mẹ́tà ìgbéyàwó àti oṣù mẹ́rin tó bímọ * Pàtàkí ìrántí 'May 30' nínú ìtàn ogun abẹ́lé


Naijiria End of Èyítí A Ń Kà Jùlọ Skip X post, 1 ALLOW X CONTENT? This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using


cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'. Warning: Third party


content may contain adverts End of X post, 1 Content is not available View content on XBBC kò mọ̀ nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta. KI NI KUMUYI SE FUN ỌMỌ YORUBA? Bawo


ni o ṣe yẹ ki awọn adari ẹsin maa sọrọ nipa awọn adari oṣelu? Ibeere yii lo jẹ yọ ni ọjọ Aje bi ọpọ ọmọ Naijiria ṣe n bẹnu ẹ̀tẹ́ lu Adari ijọ Deeper Life, Pasitọ William Kumuyi lori ọrọ rẹ


nipa olori Naijiria, Aarẹ Muhammadu Buhari. Kumuyi sọ ni iwaasu rẹ ni ijọ olu ijọ Deeper Life to wa ni Gbagada nilu Eko pe ko tọ si ọmọ Naijiria lati maa bẹnu ẹ̀tẹ́ lu awọn adari wọn. * N kò


gba owó rí lọ́wọ́ olùdíje kó tó dé ipò - Oyedepo * Wòlí ní Gbenga Adeboye jẹ nígbà ayé rẹ * Èmi kìí se Ọlọ́run, ẹ yé lo fọ́tò mí fún ẹ̀bùn - Adeboye * Nàìjíríà bá RCCG, ìyá Folu Adeboye yọ


ayọ̀ 70 Alufaa Kumuyi ni, "Ẹ ma bẹnu ẹ̀tẹ́ lu adari Naijiria. Ẹ ma sọrọ alufansa si i lori ayelujara, Facebook, iwe iroyin tabi Twitter. E ma ṣe oun kankan si i, nkan ti ko buyi kun un


ni." Alufaa naa ni ki ọmọ Naijiria bu ọla fun ẹni ti ọla ba tọ si. * Ẹ fura o, wọ́n ti ń fi orúkọ Adeboye àti Olukọya lu jìbìtì ní Facebook * 'Kọ́kọ́ kànsí àlúfà lórí ọ̀rọ̀


ìgbéyàwó' * Kí la tún gbọ́ nípa ìdámẹ́wàá? * Pọ̀pọ̀-ṣìnṣìn fún ìsìnkú ìyálódé Ibadan bẹ̀rẹ̀ O tun ni ki awọn ọmọ Naijiria ma bẹnu ẹ̀tẹ́ lu awọn gomina ati awọn olori ilu, ni ọpọ awọn to


ka iroyin naa ba lọ ori Twitter lati tabuku arọwa alufaa naa. Minisita fun eto irinna ofurufu nigba kan ri, Femi Fani-Kayode ni ọrọ Kumuyi yii jẹ ibanujẹ fun awọn akọni to ti ja fun ẹsin


Kristẹni ni atijọ. Skip X post, 2 ALLOW X CONTENT? This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other


technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'. Warning: Third party content may contain


adverts End of X post, 2 Content is not available View content on XBBC kò mọ̀ nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta. Reno Omokri to jẹ oluranlọwọ pataki Aarẹ ana, Goodluck


Jonathan, ni ti aarẹ ba ṣe daradara, oun maa n gboriyin fun un, ṣugbọn to ba ṣe nkan abuku, oun yoo tun bẹnu ẹtẹ lu u. O ni Bibeli ti Kumuyi ti yan ọrọ rẹ naa ni oun n tẹle lati ba wọn sọrọ


atunṣe s'awọn adari ti kọ ba ṣe daradara. Skip X post, 3 ALLOW X CONTENT? This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may


be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'. Warning: Third


party content may contain adverts End of X post, 3 Content is not available View content on XBBC kò mọ̀ nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta. Sẹnetọ Shehu Sani naa sọ si


ọrọ naa. O rọ Kumuyi ki o jẹ ki ọmọ Naijiria fi ero wọn han lori awọn adari wọn. Skip X post, 4 ALLOW X CONTENT? This article contains content provided by X. We ask for your permission


before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose


'accept and continue'. Warning: Third party content may contain adverts End of X post, 4 Content is not available View content on XBBC kò mọ̀ nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó


tí ó wà ní ìta. * Nàìjíríà yóò dá ṣèríà fún Senegal lónìí- Balógun Flying Eagles * Donald Trump ti pàdé Ọbabìnrin Elisabeth tilẹ̀ Gẹ̀ẹ̀sì * Sìgá mímu ń di èèwọ̀ oògùn ìlera pípé lagbaye *


Iléeṣé MTN ti san bíliọnù N55 owó ìtanràn wọn tó kù -MTN Ṣugbọn awọn ọmọ Naijiria kan ni ko si oun to buru ninu ọrọ Kumuyi naa. Skip X post, 5 ALLOW X CONTENT? This article contains content


provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before


accepting. To view this content choose 'accept and continue'. Warning: Third party content may contain adverts End of X post, 5 Content is not available View content on XBBC kò mọ̀


nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta. Awọn kan ni ootọ ọrọ ti ko ni ki a ma sọ ohun ni ọrọ Babab Kumuyi Skip X post, 6 ALLOW X CONTENT? This article contains content


provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before


accepting. To view this content choose 'accept and continue'. Warning: Third party content may contain adverts End of X post, 6 Content is not available View content on XBBC kò mọ̀


nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta. * Amẹ́ríkà ń béèrè ìròyìn facebook, email arìnrìnàjò tó f'ẹ́ gbà'wé àṣẹ * Ibanuje d'orí agbà k'odò, Ruiz fi ẹ̀ṣẹ́


sọ Anthony Joshua di ọmọ ológo àná * Sultan pàṣẹ fún àwọn mùsùlùmí láti ṣ'ọdẹ òṣùpá lónìí * 'Ọmọ SS 1 mu èso olómi, ṣùgbọ́n ilé ìwé wa kọ́ ló kú sí' Skip X post, 7 ALLOW X


CONTENT? This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie


policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'. Warning: Third party content may contain adverts End of X post, 7 Content is not


available View content on XBBC kò mọ̀ nípa àwọn ohun tí ó wà ní àwọn ojú òpó tí ó wà ní ìta. ÀWỌN ÌRÒYÌN MÌÍRÀN TÍ Ẹ LÈ NÍFẸ̀Ẹ́ SI: * N kò gba owó rí lọ́wọ́ olùdíje kó tó dé ipò - Oyedepo *


Leah Sharibu pé ọmọ ọdún 16 ní àhámọ́ Boko Haram * Pápà mímọ́ gbarata lóríi ìpànìyàn Benue * Pásítọ̀ bẹ́'rí ọmọ ìjọ ní ìpínlẹ̀ Ògùn * Ààwẹ̀ gbẹ̀mí ọmọ Naijiria ní orílẹ̀èdè Amẹ́ríkà


Trending News

Igbo olodumare: ohun gbogbo tó wà nínú ìwé fagunwa ló wà nínú igbó náà - bbc news yorùbá

IGBO OLODUMARE: OHUN GBOGBO TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ FAGUNWA LÓ WÀ NÍNÚ IGBÓ NÁÀ 12 Ọ̀pẹ̀̀ 2020 Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn 26 Èr...

Jeneba Badmus

ABOUT Jeneba Badmus is a project analyst for the Center to Champion Nursing in America (CCNA), an initiative of AARP Fou...

https://www.journaldemontreal.com/2022/12/23/le-rappeur-tory-lanez-juge-coupable-davoir-tire-sur-la-chanteuse-megan-thee-stallion-en-2020 2022-12-24T0

https://www.journaldemontreal.com/2022/12/23/le-rappeur-tory-lanez-juge-coupable-davoir-tire-sur-la-chanteuse-megan-thee...

https://www.journaldemontreal.com/2022/01/26/sante-mentale--la-detresse-toujours-en-hausse 2022-01-26T16:52:46-05:00 https://www.journaldemontreal.com

https://www.journaldemontreal.com/2022/01/26/sante-mentale--la-detresse-toujours-en-hausse 2022-01-26T16:52:46-05:00http...

Mide funmi martins: wo ohun tí a mọ̀ nípa ikú oṣèré funmi martins tí ọ̀rọ̀ ìfẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú shina peters wú síta - bbc news yorùbá

MIDE FUNMI MARTINS: WO OHUN TÍ A MỌ̀ NÍPA IKÚ OṢÈRÉ FUNMI MARTINS TÍ Ọ̀RỌ̀ ÌFẸ́ RẸ̀ PẸ̀LÚ SHINA PETERS WÚ SÍTA 23 Èrèl...

Latests News

Kumuyi bible: ọdún mẹ́ẹ̀dógún ni òun àtàwọn onímọ̀ yorùbá fi ṣe ìwádìí nípa bíbélì náà - bbc news yorùbá

KUMUYI BIBLE: ỌDÚN MẸ́Ẹ̀DÓGÚN NI ÒUN ÀTÀWỌN ONÍMỌ̀ YORÙBÁ FI ṢE ÌWÁDÌÍ NÍPA BÍBÉLÌ NÁÀ 3 Òkùdu 2019 Ìgbà tí a ṣe àfíku...

Ìtàn mánigbàgbé: ó pé ọdún mẹ́rìnlélàádọ̀ta tí akintola kú, ìdí abájọ ìja rẹ̀ pẹ̀lú awolowo rè é - bbc news yorùbá

ÌTÀN MÁNIGBÀGBÉ: Ó PÉ ỌDÚN MẸ́RÌNLÉLÀÁDỌ̀TA TÍ AKINTOLA KÚ, ÌDÍ ABÁJỌ ÌJA RẸ̀ PẸ̀LÚ AWOLOWO RÈ É 15 Sẹ́rẹ́ 2020 IKU OGUN...

Mide funmi martins: wo ohun tí a mọ̀ nípa ikú oṣèré funmi martins tí ọ̀rọ̀ ìfẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú shina peters wú síta - bbc news yorùbá

MIDE FUNMI MARTINS: WO OHUN TÍ A MỌ̀ NÍPA IKÚ OṢÈRÉ FUNMI MARTINS TÍ Ọ̀RỌ̀ ÌFẸ́ RẸ̀ PẸ̀LÚ SHINA PETERS WÚ SÍTA 23 Èrèl...

https://www.journaldemontreal.com/2022/01/26/sante-mentale--la-detresse-toujours-en-hausse 2022-01-26T16:52:46-05:00 https://www.journaldemontreal.com

https://www.journaldemontreal.com/2022/01/26/sante-mentale--la-detresse-toujours-en-hausse 2022-01-26T16:52:46-05:00http...

https://www.journaldemontreal.com/2022/12/23/le-rappeur-tory-lanez-juge-coupable-davoir-tire-sur-la-chanteuse-megan-thee-stallion-en-2020 2022-12-24T0

https://www.journaldemontreal.com/2022/12/23/le-rappeur-tory-lanez-juge-coupable-davoir-tire-sur-la-chanteuse-megan-thee...

Top