Ìtàn mánigbàgbé: ó pé ọdún mẹ́rìnlélàádọ̀ta tí akintola kú, ìdí abájọ ìja rẹ̀ pẹ̀lú awolowo rè é - bbc news yorùbá

Bbc

Ìtàn mánigbàgbé: ó pé ọdún mẹ́rìnlélàádọ̀ta tí akintola kú, ìdí abájọ ìja rẹ̀ pẹ̀lú awolowo rè é - bbc news yorùbá"

Play all audios:

Loading...

ÌTÀN MÁNIGBÀGBÉ: Ó PÉ ỌDÚN MẸ́RÌNLÉLÀÁDỌ̀TA TÍ AKINTOLA KÚ, ÌDÍ ABÁJỌ ÌJA RẸ̀ PẸ̀LÚ AWOLOWO RÈ É 15 Sẹ́rẹ́ 2020 IKU OGUN NII PA AKIKANJU, IKU ODO NII PA OMUWẸ. Oni ọjọ Iṣẹgun, ọjọ kẹẹdogun,


oṣu kinni, ọdun 2020 lo pe ọdun mẹrinlelaadọrin tawọn ologun ṣekupa Samuel Ladoke Akintola to jẹ Aare Ona Kakanfo kẹtala ilẹ Yoruba. Akintola to jẹ alakoso ijọba apa iwọ oorun Naijiria nigba


naa wa lara awọn gbajugbaja oloṣelu tawọn ologun ti wọn ditẹ gbajọba awarawa lọdun 1966. Ilu Ibadan tii ṣe olu-ilu ijọba apa iwọ oorun Naijiria ni wọn pa Akintola si ninu iditẹ-gbajọba ti


wọn ti pa ọpọ oloṣelu to jẹ ọmọ ẹgbẹ NPC (Northern People's Congress). A bi Akintola lọjọ kefa, oṣu keje, ọdun 1910 si idile Akintola Akinbola and Akanke niluu Ogbomoṣo to wa labẹ


ipinlẹ Oyo bayii. Skip Èyítí A Ń Kà Jùlọ and continue reading ÈYÍTÍ A Ń KÀ JÙLỌ * Ọwọ́ ológun Nàìjíríà tẹ ṣọ́ja 18, ọ̀lọ́pàá 15, fẹ̀sùn kan àwọn àjọ òkèèrè tó ń ṣe agbódegbà fáwọn


agbésùnmọ̀mí * Ìtàn ayé Orúgbó, ìyá àgbà tó dá ìlú Omu-Aran sílẹ̀ ní 13th Century àmọ̀ tí wọn ‘ló wa láyé di òní’ * Pàtàkí ìrántí 'May 30' nínú ìtàn ogun abẹ́lé Naijiria * Regina


Chukwu sọ ìdí tí ọkọ rẹ̀ ṣe ní kò gún òun ní abẹ́rẹ́ ikú lẹ́yìn ọdún mẹ́tà ìgbéyàwó àti oṣù mẹ́rin tó bímọ End of Èyítí A Ń Kà Jùlọ Nigba ti Akintola wa ni kekere ni baba rẹ to jẹ oniṣowo ko


ẹbi rẹ lọ si ilu Minna. * Àgbẹ́kọ̀yá yarí; Afẹnífẹ́re ní ilé ẹjọ́ ló kàn lórí ọ̀rọ̀ Àmọ̀tẹ́kùn * Aláàfin Ọyọ: Ọba tó bá n mú ọtí ní ìta kò yẹ ní ẹni tàá bọ̀wọ̀ fún * Bí ìtàn ayé Toyosi


Arigbabuwo ṣe lọ rèé láti ẹnu Musiliu Dasofunjo àti Ogun Majek * Imam tó fẹ́ ọkùnrin míì níyàwó forí kó ìjìyà òfin ETO ẸKỌ AKINTOLA Akintola bẹrẹ eto ẹkọ rẹ nile iwe Church Missionary


Society school niluu Minna to jẹ olu-ilu ipinlẹ Niger lonii. Akintola pada si ilu Ogbomoṣo lọdun 1922 lati maa gbe pẹlu awọn baba baba rẹ, nibẹ lo ti lọ ile iwe Baptist day school. Akintọla


tẹsiwaju ẹkọ rẹ nile iwe Baptist College lọdun 1925. Akintola ṣiṣẹ olukọ nile iwe Baptist Academy lati ọdun 1930 si ọdun 1942, ko too lọ ṣiṣẹ ni ile iṣẹ Reluwe. AKINTOLA WỌ AGBO OṢELU Lẹyin


to kẹkọọ gboye tan nilẹ Gẹẹsi gẹgẹ bi agbẹjọro, Akintola pada si Naijiria lọdun 1949. Lẹyin naa lo darapọ mọ awọn ti wọn ti kawe gboye mii lapa iwo oorun Naijiria lati da ẹgbẹ oṣelu Action


Group (AG) silẹ pẹlu ifari Oloye Obafemi Awolowo. Akintola kọkọ di ipo oludamọran lori ọrọ ofin ẹgbẹ naa mu ko to di igbakeji adari ẹgbẹ oṣelu AG lọdun 1953 lẹyin iku Bode Thomas. Gẹgẹ bi


igbakeji adari ẹgbẹ, Akintola ko ṣiṣẹ ninu ijọba apa iwọ oorun Naijiria ti Oloye Awolowo jẹ alakoso rẹ. Ṣugbọn oun ni adari ẹgbẹ osẹlu AG nile aṣoju-ṣofin Naijiria lapaapọ nibi to ti jẹ


olori ẹgbẹ oṣelu alatako. Akintọla jẹ minisita eto ilera, ibaraẹnisọrọ ati minisita ọkọ ofurufu. Ọrọ lori iṣejọba ajumọlo ninu ẹgbẹ oṣelu AG lo mu ki edeaiyede ṣẹlẹ laarin Akintola ati


Awolowo. Akintola tako igbesẹ ẹgbẹ AG pẹlu idari Awolowo lori asopọ pẹlu ẹgbẹ oṣelu mii, Akintola ni awọn ẹya Igbo ni wọn n jẹ anfaani eto ọhun ju. * Ọ̀rẹ́ mi tímọ́tímọ́ tí a jọ ń ja ogun


Biafra ní kí n yìnbọn pa òun- Gabriel Aladejebi * Àsọtẹ́lẹ̀ Fada Mbaka, tó yẹ àga mọ́ gómìnà Imo nídìí rèè * Ilé ẹjọ́ rán ọmọ ìjọ lẹ́wọ̀n ọdún 18 lórí ẹ̀sùn pé ó jí ₦ 15m owo ìjọ * Ìjàmbà


ọkọ̀ akẹ́rù ní Ikòròdú fa súnkẹrẹ-fàkẹrẹ ọkọ̀ ní Márosẹ̀ EDEAIYEDE LAARIN AWOLOWO ATI AKINTOLA Awolowo fẹsun kan Akintola pe o fẹ fi eeru gba ipo olori ẹgbẹ oṣelu AG mọ oun lọwọ. Rogbodiyan


bẹ silẹ nile igbimọ aṣofin ijọba apa iwọ oorun Naijiria lẹyin tawọn aṣofin kan dibo lati yọ Akintola nipo lọdun 1962. Rogbodiyan ọhun lo jẹ ki ile aṣofin ijọba apa iwọ oorun Naijiria pin si


meji. * Naira Marley ti tèṣù mọ́lẹ̀ nílé ẹjọ́ májísíréètì lórí ẹ̀sùn ìjọ́kọ̀gbé * Aláàfin Ọyọ: Ọba tó bá n mú ọtí ní ìta kò yẹ ní ẹni tàá bọ̀wọ̀ fún * Àwọn omidan Naijiria ni wọ́n fi ń ṣerú


ní Lebanon- Ọmọlọla * Bí ìtàn ayé Toyosi Arigbabuwo ṣe lọ rèé láti ẹnu Musiliu Dasofunjo àti Ogun Majek Rogbodiyan yii lo jẹ ki olootu ijọba Naijiria nigba naa, Sir Abubakar Tafawa Balewa


kede ko nile o gbele nilẹ Yoruba. O si fi Oloye M.A Majekodunmi, to jẹ minisita eto ilera nigba naa gẹgẹ bi alakoso ijọba. Lẹyin ọ rẹyin, Akintola pada gba ipo rẹ gẹgẹ bi alakoso ijọba apa


iwọ oorun Naijiria lọdun 1963. Akintola tun wọle ibo gbogbogbo ọdun 1965 ṣugbọn o dije ninu eto idibo naa gẹgẹ bi adrari ẹgbẹ oṣelu tuntun Nigerian National Democratic Party (NNDP). Ẹgbẹ


oṣelu NNDP ni ajọsẹpọ pẹlu Northern People's Congress (NPC) to n ṣakoso ijọba apapọ nigba naa. * Irọ̀ ni ìjọba ń pa, Ikọ Amọtẹkun ba ofin Naijiria mu- Ìgbìmọ̀ Yoruba * Wo ohun tó yẹ kó


mọ̀ nípa Gomina Imo ti ilé ẹjọ́ giga ye àga mọ́ nídí * Ọ̀pọ̀ àwòrán tó ń ṣeni láàánú rèè nípa ogun abẹ́lé Nàíjíríà * Èyí ni bí ogun abẹ́lé Biafra ṣe bẹ̀rẹ̀ ní Nàìjíríà IDILE AKINTOLA


Akintola ṣe igbeyawo pẹlu Oloye Faderera Akintola, Eleduwa si fi ọmọ marun un jinki wọn. Meji ninu ọmọ rẹ, Oloye Yomi Akintola and Dokita Abimbola Akintola naa jẹ minisita keji fun eto


inawo. Yomi Akintola tun fi igba kan jẹ aṣoju ijọba orilẹ-ede Naijiria ni Hungary, bakan naa ni iyawo ọmọ rẹ kan, Dupe Akintola jẹ aṣoju ijọba Naijiria ni Jamaica. * Àsọtẹ́lẹ̀ Fada Mbaka, tó


yẹ àga mọ́ gómìnà Imo nídìí rèè * Wo ipa tí Mayegun yóò ma kó ní ilẹ̀ Yoruba! * Àgbẹ́kọ̀yá yarí; Afẹnífẹ́re ní ilé ẹjọ́ ló kàn lórí ọ̀rọ̀ Àmọ̀tẹ́kùn * Ilé ẹjọ́ rán ọmọ ìjọ lẹ́wọ̀n ọdún 18


lórí ẹ̀sùn pé ó jí ₦ 15m owo ìjọ


Trending News

Igbo olodumare: ohun gbogbo tó wà nínú ìwé fagunwa ló wà nínú igbó náà - bbc news yorùbá

IGBO OLODUMARE: OHUN GBOGBO TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ FAGUNWA LÓ WÀ NÍNÚ IGBÓ NÁÀ 12 Ọ̀pẹ̀̀ 2020 Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn 26 Èr...

Jeneba Badmus

ABOUT Jeneba Badmus is a project analyst for the Center to Champion Nursing in America (CCNA), an initiative of AARP Fou...

https://www.journaldemontreal.com/2022/12/23/le-rappeur-tory-lanez-juge-coupable-davoir-tire-sur-la-chanteuse-megan-thee-stallion-en-2020 2022-12-24T0

https://www.journaldemontreal.com/2022/12/23/le-rappeur-tory-lanez-juge-coupable-davoir-tire-sur-la-chanteuse-megan-thee...

https://www.journaldemontreal.com/2022/01/26/sante-mentale--la-detresse-toujours-en-hausse 2022-01-26T16:52:46-05:00 https://www.journaldemontreal.com

https://www.journaldemontreal.com/2022/01/26/sante-mentale--la-detresse-toujours-en-hausse 2022-01-26T16:52:46-05:00http...

Mide funmi martins: wo ohun tí a mọ̀ nípa ikú oṣèré funmi martins tí ọ̀rọ̀ ìfẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú shina peters wú síta - bbc news yorùbá

MIDE FUNMI MARTINS: WO OHUN TÍ A MỌ̀ NÍPA IKÚ OṢÈRÉ FUNMI MARTINS TÍ Ọ̀RỌ̀ ÌFẸ́ RẸ̀ PẸ̀LÚ SHINA PETERS WÚ SÍTA 23 Èrèl...

Latests News

Ìtàn mánigbàgbé: ó pé ọdún mẹ́rìnlélàádọ̀ta tí akintola kú, ìdí abájọ ìja rẹ̀ pẹ̀lú awolowo rè é - bbc news yorùbá

ÌTÀN MÁNIGBÀGBÉ: Ó PÉ ỌDÚN MẸ́RÌNLÉLÀÁDỌ̀TA TÍ AKINTOLA KÚ, ÌDÍ ABÁJỌ ÌJA RẸ̀ PẸ̀LÚ AWOLOWO RÈ É 15 Sẹ́rẹ́ 2020 IKU OGUN...

Mide funmi martins: wo ohun tí a mọ̀ nípa ikú oṣèré funmi martins tí ọ̀rọ̀ ìfẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú shina peters wú síta - bbc news yorùbá

MIDE FUNMI MARTINS: WO OHUN TÍ A MỌ̀ NÍPA IKÚ OṢÈRÉ FUNMI MARTINS TÍ Ọ̀RỌ̀ ÌFẸ́ RẸ̀ PẸ̀LÚ SHINA PETERS WÚ SÍTA 23 Èrèl...

https://www.journaldemontreal.com/2022/01/26/sante-mentale--la-detresse-toujours-en-hausse 2022-01-26T16:52:46-05:00 https://www.journaldemontreal.com

https://www.journaldemontreal.com/2022/01/26/sante-mentale--la-detresse-toujours-en-hausse 2022-01-26T16:52:46-05:00http...

https://www.journaldemontreal.com/2022/12/23/le-rappeur-tory-lanez-juge-coupable-davoir-tire-sur-la-chanteuse-megan-thee-stallion-en-2020 2022-12-24T0

https://www.journaldemontreal.com/2022/12/23/le-rappeur-tory-lanez-juge-coupable-davoir-tire-sur-la-chanteuse-megan-thee...

Jeneba Badmus

ABOUT Jeneba Badmus is a project analyst for the Center to Champion Nursing in America (CCNA), an initiative of AARP Fou...

Top